Ìtumọ̀ ọ̀hàhà ní èdè Yorùbá:

ọ̀hàhà

Àmì ohùn /do do do/

Ɔ̀ɾƆ̀-OɾÚKƆ

  • mímú òngbẹ tí ó máa ń gbẹ ènìyàn, pàápàá ní ìrìn àjò

    Mo ronú nípa irú ọ̀hàhà tí ọ́ lè pa àwọn tí wọ́n re kọjá aginjù Sàhárà ní ayé àtijọ́.
    òngbẹ

Ìsun