Ɔ̀ɾƆ̀-OɾÚKƆ
-
ẹrù tí a dì sí inú aṣọ tàbí àpò tí ó rí bàm̀bà
“Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, àwọn ọmọ náà yí òketè tí ohun-èlò ìpidán wọn wà nínú rẹ̀ lọ sí òde; wọ́n ta'á rù, wọ́n sì tẹ̀lé ọ̀gá'a wọn.”
Ìsun
Èdè Yorùbá. Ìtumọ̀ àti àpẹẹrẹ èkíní wá láti: Ògúnníran, L. “Eégún Aláré” (1985, ewé 3 & 82). Macmillan Nigeria Publishers Ltd.