Ìtumọ̀ aginjù ní èdè Yorùbá:

aginjù

Ohùn /re re do/

ɔ̀ɾɔ̀-oɾúkɔ

  • agbègbè ilẹ̀ tí ènìọ̀ kọnkọn kò gbèé n’íbẹ̀, tí ó sì lè jẹ́ pé ilẹ̀ nọ́ọ̀ kò tíì tọ́ láti ṣe gbé

    Ogún lé wọn kúrò láti abúlé’e wọn ni ó fi wa jẹ́ pé aginjù ni wọ́n ṣí ìbùdòó sí.
    • Láti aginjù ni wọ́n tẹ́ ìlú nọ́ọ̀ dó.
    ijù

Ìsun