Ìtumọ̀ fúnká ní èdè Yorùbá:

fúnká

Àmì ohùn /mi mi/

(Kíkọ Òmíràn  fọ́nká)

Ọ̀RỌ̀-ÌṢE

  • kí nǹkan pín, bẹ́, tàbí fọ́ sí ẹ̀là oríṣiríṣi

    Ó ti ṣe wá jẹ́ tí gbogbo wa fúnká, tí a kò sí ní ojú kan náà, tí a fi ní ẹ̀ka èdè tí ó pín yẹ́lẹyẹ̀lẹ ní òde òní?
    túká
    sopọ̀, lọ́pọ̀

Ìsun

Èdè Yorùbá. Ìmísí ti àpẹẹrẹ èkíní fún ìtumọ̀ èkíní wá láti: T. Ọ̀pádọ̀tun àti àwọn ìyókù. “Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá Fún Ilé-Ẹ̀kọ́ Olùkọ́ni Àgbà: Àkójọpọ̀ Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá (Atọ́nà Akẹ́kọ̀ọ́)” (2000, ewé 145). Visual Resources Publishers. Ìbàrá, Abẹ́òkúta.