Ìtúùmɔ̀:

ẹtu

Ohũ̀ /re re/

ɔ̀ɾɔ̀-oɾúkɔ

Ɛɾɔ̃ (Philantomba maxwellii)
  • ẹrọn ìdọdẹ tí ó kéré ju èsùúró

òwe

    ‘Ọlọ́run ḿ bẹ, Ọlọ́run ḿ bẹ’ ní ń kpa ẹtu, ‘Ọlọ́run ḿ bẹ, èèyọ̀n’ọ́n wà’ ní ń la àgbọ̀nrìín.