Ìtumọ̀ àsìíá ní èdè Yorùbá:

àsìíá

Ohũ̀ /do domi mi/

ɔ̀ɾɔ̀-oɾúkɔ

  • aṣọ tí a so mọ́ ọ̀pá tí ó lè ní àwọ̀ ọ̀kan tàbí onírúurú àti àwòrán tí ó sì jẹ́ àmì nǹkan pàtàkì bí'i ìlú, ẹgbẹ́, tàbí ìhìn

    Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ogun aṣòfò gbé àsíá funfun sí òkè ọ̀pá kí àwọn aṣẹ́gun lè mọ̀ wí pé ìjà ti parí, àwọn ti túnba.
    • Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìlú ni wọ́n ní àsíá aláwọ̀ mẹ́ta.