Ìtumọ̀ wáhàrì ní èdè Yorùbá:

wáhàrì

Ohũ̀ /mi do do/

ɔ̀ɾɔ̀-oɾúkɔ

  • ẹrú obìnrin tí ó wá di aya ọ̀gá'a rẹ̀

    Ajagun wí pé, “Lẹ́hìn ogun, ó di dandan kí àwọn ẹrú-obìrin ẹlẹ́wà di wáhàrì láì-pẹ́.”
    • Ó wọ́pọ̀ ní àtọjọ́mọ́jọ́ kí ẹrú-obìnrin di wáhàrì ọ̀gá'a rè.