Ọ̀RỌ̀-ÌṢE
-
kí nǹkan pín, bẹ́, tàbí fọ́ sí ẹ̀là oríṣiríṣi
Ó ti ṣe wá jẹ́ tí gbogbo wa fúnká, tí a kò sí ní ojú kan náà, tí a fi ní ẹ̀ka èdè tí ó pín yẹ́lẹyẹ̀lẹ ní òde òní?túkásopọ̀, lọ́pọ̀
Ìsun
Èdè Yorùbá. Ìmísí ti àpẹẹrẹ èkíní fún ìtumọ̀ èkíní wá láti: T. Ọ̀pádọ̀tun àti àwọn ìyókù. “Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá Fún Ilé-Ẹ̀kọ́ Olùkọ́ni Àgbà: Àkójọpọ̀ Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá (Atọ́nà Akẹ́kọ̀ọ́)” (2000, ewé 145). Visual Resources Publishers. Ìbàrá, Abẹ́òkúta.