Ìtumọ̀ àwọ̀n ní èdè Yorùbá:

àwọ̀n

Ohũ̀ /do do/

ɔ̀ɾɔ̀-oɾúkɔ

  • ohun tí ó ní okùn-òwú tàbí okùn-irin ní síso tí ó sì ní onírúurú èlò, bí fún pípẹja, ọkọ̀ fífà, abbl.

    Apẹja kò lè ká ẹja rẹpẹtẹ ní ọjọ́ kan ṣoṣo láì lò àwọ̀n.